Playing
Yoruba > Proverbs(Photos) More
Members (Yoruba > Proverbs) More
Yoruba >> Proverbs(Featured Translations)
Igbo: ị na-arahụ kwa anya ma ebe nchekwa gị na-adịgide ndụ ị bụ a N'ọgbụgba égbè kpakpando ma ọ bụrụ na naanị anya mmiri m nwere ike na-ewetara gị azụ i ga-eti g...
Asked by: oki richard .
Translations (1) .
Translate
to
Igbo
English: beware of a dog that has oil in it's mouth
Asked by: Isichei Tochi .
Translations (1) .
Translate
to
English
Yoruba >> Proverbs
Yoruba >> Proverbs: Gbòngbò kan ṣoṣo kò gbọdọ̀ ré ọ̀jọ̀gbọ́n lẹ́ẹ̀pa lẹ́ẹ̀mejì /
The same tree stump shouldn't trip a wise person twice.
[Once beaten, twice shy]
Yoruba_Proverbs .
Translations (1) .
Add Translation
Yoruba >> Proverbs: Pàṣán tí a bá fi lé òṣì lọ, ẹnìkan kì í sọ ọ́ nù
No one throws away the cane used to drive away poverty from his or her life.
[No one toys with the foundation of his or her success.]
Yoruba_Proverbs .
Translations (1) .
Add Translation
Yoruba >> Proverbs: Ofin ti a ba tori eru se a o le titori omo daanu
Mhizgbemz .
Translations (1) .
Add Translation
Yoruba >> Proverbs: Hùnrùnhunrun ni yóò pọ̀, ẹlẹ́dẹ̀ wa á dé Ọ̀yọ́. /
Its grunting may be endless; but our pig would get to Oyo town, eventually.
[Keep up hope; if you won't give up, you would win.]
Yoruba_Proverbs .
Translations (1) .
Add Translation
Yoruba >> Proverbs: Bí kò bá ń’ìdí obìrin kì í jé
Yoruba_Proverbs .
Translations (1) .
Add Translation
Yoruba_Proverbs .
Translations (2) .
Add Translation
Yoruba >> Proverbs: Bí èèyàn ò bá tọ̀ sí ojú kan, kì í hó
If one does not urinate on a single spot, the urine won't foam.
[Be focused; don't spread yourself thin.]
Yoruba_Proverbs .
Translations (1) .
Add Translation
Yoruba >> Proverbs: Ẹni bá ńsọ òkò sí adìyẹ igba, òkò ló máa sọ tílẹ̀ á fi...(more)
Yoruba_Proverbs .
Translations (1) .
Add Translation
Yoruba >> Proverbs: o ti yoo mu miran si isalẹ ninu ẹrẹ gbọdọ duro ninu ẹrẹ lati pa fun u
Yoruba_Proverbs .
Translations (1) .
Add Translation
Yoruba >> Proverbs: Tí irọ́ bá lọ lógún ọdún, ọjọ́ kan ṣoṣo ni òótọ́ yóò ba.
Yoruba_Proverbs .
Translations (1) .
Add Translation
Say something and translate it into Hausa, Igbo, Pidgin or Yoruba. Find names, words, proverbs, jokes, slangs in Nigerian languages, and their meaning. Share photos and translations, record pronunciations, make friends. | An NgEX brand